Adupë löwö rë fun rira ni Sony Ericsson S312. Fun akoonu
foonu ni afikun, lö si www.sonyericsson.com/fun. Fi orukö silë
ni isiyi lati gba ibi itöju, ori ayelujara ati ipese pataki,awön iroyin
ati idije ni www.sonyericsson.com/myphone. Fun atilëyin öja,
lö si www.sonyericsson.com/support.
Awön aami ilana
Awö ami atële wönyi lee han ninu itöni Olumulo:
>Lo bötini lilö kiri lati yi lö ko si yan
Të bötini ašayan laarin
Të bötini lilö kiri si oke
Të bötini lilö kiri si isalë
Të bötini lilö kiri si apa osi
Të bötini lilö kiri si apa ötun
Akösilë
Italolobo
Ikilö
Jöwö ka Alaye pataki šaaju ki o to lo foonu alagbeka rë.
Kaadi (Subscriber Identity Module) SIM, ti o gba lati ödö
onišë nëtiwöki rë, ni alaye nipa šišë alabapin rë ninu.
Paa foonu rë nigba gbogbo ki o si yö šaja ati batiri
na šaaju ki o to fi sii tabi yöö kaadi SIM kuro.
O le fi awön olubasörö pamö sori kaadi SIM šaaju ki o to
yö kuro lati inu foonu rë. Wo Awön olubasörö loju iwe 27.
Koodu PIN (kökörö kaadi SIM)
O le nilo PIN (Personal Identification Number) lati mu awön išë
ati išë inu foonu rë šišë. Onišë nëtiwöki rë ti pese PIN rë. PIN
oni-nömba köökan yoo han bi *, ayafi ti o ba bëërë pëlu oni-nömba
pajawiri, fun apëërë, 112 tabi 911. O le wo ati pe nömba pajawiri
laisi titë PIN sii. Lati lo titiipa kaadi SIM tabi yi koodu PIN pada,
ri Titiipa kaadi SIM loju iwe 35.
Ti o ba të PIN ti ko tö si ni igba mëta ni öna kana, o ti dina
mö kaadi SIM. Ri Titiipa kaadi SIM loju iwe 35.
Foonu rë še awön atilëyin Memory Stick Micro™ (M2™) kaadi
iranti, fifi aaye ibi-itöju aaye dië ë sii kun fun foonu rë. O tun le
šee lo bi kaadi iranti to šee gbe pëlu awön ërö miiran to baramu.
O le gbe akoonu laarin kaadi iranti ati iranti foonu. Wo Ere idaraya
loju iwe 14 ati Išë-öna ërö alailowaya Bluetooth™ loju iwe 30.
Lati fi kaadi iranti sii
1 Yö ideri ëyin kuro.
2 Ja batiri naa kuro.
3 Fi kaadi iranti si ninu pëlu awön olubasörö alawö wura
to ndoju kölë.
Lati yöö kaadi iranti
1 Yö ideri ëyin kuro.
2 Ja batiri naa kuro.
3 Të eti kaadi iranti lati tusilë ati lati yöö kuro.
1 So šaja pö mö foonu pëlu aami agbara ori šaja ti nköju si öna
oke. Yoo gba to wakati 3.5 o pöju lati gba agbara si batiri
ni kikun. Të bötini kan lati wo iboju ki o wo ipo gbigba agbara.
2 Lati yöö šaja kuro, të pulöögi si öna oke.
Yoo gba to išeju dië šaaju ki aami batiri to han loju iboju.
O lee lo foonu nigbati o ba ngba agbara löwö. O le gba
agbara si batiri nigbakugba dië ë sii tabi kere si wakati 3.5.
Idilöwö gbigba agbara ko ba batiri jë.
Aaye ifi nëtiwöki han yoo fi agbara nëtiwöki GSM han ni agbegbe
rë. O le gbe si ipo miiran ti o ba ni awön išoro pipe tabi išë nëtiwöki
agbegbe ti ko dara. Ko si nëtiwöki tunmö wipe o ko si ni ibiti
o ti le ri nëtiwöki.
= Išë nëtiwöki agbegbe to dara
= Išë nëtiwöki agbegbe aropin
Awön ipo batiri
= Batiri foonu naa ti gba agbara ni kikun
= Batiri foonu naa ti šofo
Nigbati foonu ba nlo agbara to ti gba löwö, agbara batiri
yoo ma lö silë diëdië.
Awön profaili
Aago ati öjö
Ede foonu
Awön öna abuja
Ipo ofurufu
Aabo
Ipo foonu
Tun gbogbo rë to
Awön ipe
Šiše ipe kiakia
Dari ipe
Šakoso awön ipe
Akoko ati iye owó*
Fihan/töju nö. mi
Aimudani
* Awön aköjö ašayan miiran je onišë ërö-, nëtiwöki- ati šiše alabapin-ti
o gbëkële.
** O le lo bötini lilö kiri lati yi lö laarin awön taabu inu awön akojö ašayan
inu akojö ašayan. Fun alaye dië ë sii, wo Lilö kiri loju iwe 11.
Aw.ohun & titanj
Iwön didn.oh.orin
Ohùn orin ipe
Ipo ipalölö
Titanij.pëlu gbígb.
Itaniji fun ifiranšë
Dídún bötini
Asopömöra
Bluetooth
USB
Amušišëpö*
Nëtiwöki alagbeka
Eto ayelujara
Ma še yöö okun USB kuro lati foonu tabi kömputa nigbati
gbigbe faili ba nlö löwö eyi le ba iranti foonu ati kaadi
iranti jë.
O ko ni anfani lati wo gbigbe faili ninu foonu rë titi ti o ba ti yö
okun USB kuro ninu foonu rë. Fun gige asopö okun USB,
titë-ötun ninu aami Disk yiyö kuro ni Windows Explorer
ko si yan Kö.
Ërö orin fidio
Lati mu fidio šišë
1 Lati imurasilë yan Ašayan > Olusakoso faili > Aliböömu
Gba awön gige fidio silë/
yipada lati kamëra oniduro
si kamëra fidio
3Dudu
4
Ya awön aworan/yipada
lati kamëra oniduro si
kamëra fidio
5 Awön eto
Kamëra ati agbohunsilë fidio
O le ya awön aworan ko si gba awön agekuru fidio silë lati wo,
fipamö tabi firanšë. Awön föto ati agekuru fidio ti wa ni fipamö
laiföwöyi lori kaadi iranti, ti o ba ti fi kaadi iranti sii. Ti o ba jë,
wön ti wa ni fipamö ni iranti foonu. O le wa awön aworan ti
o fipamö ati awön agekuru fidio ni Ašayan > Olusakoso faili
> Aliböömu kamëra.
1 Lati imurasilë yan Ašayan > Olusakoso faili > Aliböömu
kamëra.
2 Lö soke-sodo sori aworan ki o yan Aw. ašy. > Photo fix.
Bulöögi aworan
Bulöögi aworan jë Oju-iwe ayelujara ti ara ëni. Ti šiše alabapin
rë ba še atilëyin išë yi, o le fi awön aworan ranšë si bulöögi.
Awön išë ayelujara le beere adehun iwe-ašë lötö laarin iwö
ati olupese išë. Afikun ofin ati/tabi owo sisan le waye. Kan
si olupese išë rë.
Lati fi awön aworan kamëra ranšë si bulöögi
1 Lati imurasilë yan Ašayan > Olusakoso faili > Aliböömu
kamëra.
2 Yi lö si aworan ko si yan Aw. ašy. > Firanšë > Si bulöögi.
3 Yi lö si Aköle: ko si yan Šatnkö.
4 Fi aköle kan kun O dara.
5 Yi lö si Örö: ko si yan Šatnkö.
6 Fi örö kun ko si yan O dara.
7 Yan Se atjd.
Gbigbe awön aworan
O le lo išë-öna ërö alailowaya Bluetooth™ ati okun USB lati gbe
awön aworan ati awön agekuru fidio laarin kömputa kan ati foonu
rë. Wo Išë-öna ërö alailowaya Bluetooth™ loju iwe 30 ati Lati gbe awön faili ni ipo Ibi-itöju akopö loju iwe 16 Fun alaye dië
ë sii.
1 Lati imurasilë të mölë titi aami + yoo han.
2 Të koodu orilë-ede sii, koodu agbegbe (lai si oodo akökö)
pëlu nömba foonu.
3 Të .
Akojöpö ipe
O le wo alaye nipa awön ipe to šëšë še.
Lati ipe nömba lati inu akojöpö ipe
1 Lati imurasilë të .
2 Yi lö si orukö tabi nömba kan ko si yan .
Lati pa nömba kan rë lati inu akojö ipe
1 Lati imurasilë të .
2 Yi lö si orukö tabi nömba kan ko si yan Aw. ašy. > Paarë.
Awön ipe pajawiri
Foonu rë še atilëyin fun pipe awön nömba pajawiri ilu-okeere,
fun apëërë, 112 ati 911. Awön nömba yi še lo deede lati še
awön ipe pajawiri ni eyikeyi orilë-ede, pëlu tabi laisi kaadi SIM
ti a fi sii, ti nëtiwöki GSM ba wa ni ibiti a ti le ri.
Lati še ipe pajawiri
• Lati imurasilë të nömba pajawiri ilu-okeere, fun apëërë,
112 ko si të .
Ni awön orilë-ede mii, awön nömba pajawiri miiran le tun ti ni
igbega. Onišë nëtiwöki rë le ti fipamö awön nömba pajawiri
ti agbegbe ni afikun lori kaadi SIM rë.
O le rii daju pe oni ipa išë nömba arin ninu foonu rë. Eyi ti pese
nipa olupese isë nëtiwöki rë ti wa ni ifipamö lori kaadi SIM. O le
ni lati të nömba na si funrara rë.
Lati kö ati iföröranšë
1 Lati imurasilë yan Ašayan > Fifiranšë > Kö titun
> Iföröranšë.
2 Kö ifiranšë ko si yan Tesi.
3 Yan ašayan.
4 Yan O dara > Firanšë.
Wo Ntë örö sii loju iwe 32.
Lati fi awön ohun kan kun iföröranšë
1 Nigbati o ba nkö ifiranšë, yan Aw. ašy. > Fi ohun kan sii.
2 Yan ašayan.
Lati wo awön iföröranšë ti nwöle
1 Nigbati Ifiranšë titun lati: yoo han, yan Wo.
2 Yan ifiranšë aika.
Lati wo awön ifiranšë ti wa ni ipamö ninu apo-iwöle.
• Yan Ašayan > Fifiranšë > Apo-iwöle.
Lati gba ipo ifijišë ifiranšë
1 Lati imurasilë yan Ašayan > Fifiranšë > Eto > Iföröranšë
> Ìjábõ ifijišë.
2 Yan Tan. O ti gba ifitonileti nigbati ifiranšë ba ti wa ni ifijišë
Ifiranšë alaworan le ni örö ninu, awön aworan, awön gbigbasilë
ohun, agekuru fidio ati asomö.
O le seto profaili MMS ati adirësi fun ifiranšë olupin rë.
Ti ko ba si profaili MMS tabi olupin ifiranšë to wa, o le gba
gbogbo eto lati ayelujara laiföwöyi lati ödö onišë nëtiwöki
rë tabi ni www.sonyericsson.com/support.
Lati sëda ifiranšë alaworan
1 Lati imurasilë yan Ašayan > Fifiranšë > Kö titun > Ifiranšë
aworan.
2 Të örö sii. Lati fi awön ohun kan kun ifiranšë, të , lö soke-
sodo nipa lilo ki o si yan ohun kan.
Lati ranšë ifiranšë alaworan
1 Nigbati ifiranšë ba šetan, yan Tesi.
2 Yan ašayan.
3 Yan O dara > Firanšë.
Olufiranšë ati olugba o ti ni awön iše alabapin to nše atilëyin
fifiranšë alaworan. Rii daju pe alabapin foonu ti še awön
atilëyin gbigbe data, ati paapaa eto to tö ninu foonu rë.
O le fipamö awön orukö, awön nömba foonu ati alaye ara ëni
ni Awön olubasörö. O le fi alaye pamö sinu iranti foonu tabi
lori kaadi SIM.
Awön olubasörö aiyipada
O le yan iru alaye olubasörö ewo ni yoo han bi aiyipada. Ti Awn
olbasr foon ti yan bi aiyipada, awön olubasörö rë yoo fi gbogbo
alaye ti o ti fipamö han ninu foonu. Bi o ba yan A. olubasör SIM
gëgëbi aiyipada, awön olubasörö yoo fi awön orukö ati awön
nömba ti a fipamö sori kaadi SIM han.
Ti o ba yan Foonu & SIM bi Aw.olubasörö aypd, yoo
beere ki o yan laarin Foonu tabi Kaadi SIM nigba fifi
awön olubasörö titun kun.
Lati yan awön olubasörö aiyipada
1 Lati imurasilë yan Ašayan > Awön olubasörö.
2 Yi lö si Olubasörö titun ko si yan Aw. ašy. > To ti ni
ilösiwaju > Aw.olubasörö aypd.
3 Yan ašayan.
Fifi awön olubasörö ranšë
Lati fi olubasörö ranšë
1 Lati imurasilë yan Ašayan > Awön olubasörö.
2 Lö soke-sodo sori olubasörö kan ki o yan Aw. ašy.
> Fi olubasr ranšë.
3 Yan öna gbigbe.
Rii daju wipe ërö ti ngba wöle še atilëyin öna gbigbe
ti o yan.
O lee gba awön olubasörö foonu ti o firanšë nipa lilo imöërö alagbeka Bluetooth™. Botiwukori, awön olubasörö
ni a ngba lököökan nitoripe foonu ni o nyanju wön gëgëbi
faili vcf ëni köökan. Bi a ba fi gbogbo iwe foonu ranšë,
olubasörö akökö nikan ni a o ri gba. Fifi olubasörö ranšë
nipa lilo SMS ni ko seese.
Awön olubasörö foonu
Awön olubasörö foonu le ni awön orukö ninu, awön nömba
foonu ati alaye ara ëni. Wön ti wa ni fipamö ni iranti foonu.
Lati fikun olubasörö foonu
1 Lati imurasilë yan Ašayan > Awön olubasörö > Olubasörö
titun.
2 Yan Orukö idile: lati fikun orukö igbëhin ko si yan O dara.
3 Yan Orukö abisö: lati fikun orukö akökö si yan O dara.
4 Yan Nömba titun: lati fikun nömba ko si yan O dara.
5 Yan ašayan nömba kan.
6 Yi lö laarin awön taabu ko si yan awön aaye lati fi alaye kun.
7 Yan Fipamö.
Wo Ntë örö sii loju iwe 32.
Të aamin + ati koodu orilë-ede sii pëlu gbogbo awön
nömba Iwe foonu. Lëhinna o le lo wön lëhin-odi tabi ni ile.
Wo Lati še awön ipe si ilu okeere loju iwe 24.
Ri daju pe o yan Awn olbasr foon bi Aw.olubasörö aypd
nigbati o ba nfi olubasörö foonu kan kun.
Nipasë lilo titë örö asötëlë sii o ni lati të bötini köökan lëëkan.
Tësiwaju nipa kikö örö kan paapa ti o ba han bi išina.
Foonu naa nlo iwe-itumö lati ranti örö naa nigbati o ti të
gbogbo awön lëta sii.
Lati të örö nipa lilo titë örö asötëlë sii
1 Funn apërë, lati kö “Jane”, të , , , .
2 Ni bayi o ti ni awön ašayan pupö:
• Ti örö ti o han ba jë eyi ti o nfë, të lati gba ko si fi aaye
kun. Lati gba örö lai fi aaye kun, të .
• Ti o ba jë örö ti o fë kö lo yöju, të tabi wa ka tun yë wö
böya örö miran wa.
• Lati të aami iduro ati aami idësë sii, yan lëhinna tabi
leralera.
Lati të örö lilo multitap sii
• Të – titi ohun kikö silë ti o fë yoo han.
• Të lati fi aaye kan kun.
• Të lati të aami iduro ati aami idësë sii.
• Të lati lö laarin awön lëta oke, awön lëta isalë ati awön
Olupe le fi ifiranšë ifohunranšë silë nigbati o ko le dahun.
O le gba nömba ifohunranšë rë lati ödö onišë nëtiwöki rë.
Lati të nömba ifohunranšë sii
1 Lati imurasilë yan Ašayan > Fifiranšë > Eto > Nömba
ifohùnrnš.
2 Yi lö si nömba ifohunranšë ko si yan O dara.
3 Të nömba ifohunranšë sii ko si yan O dara.
Lati pe išë ifohunranšë rë
• Lati imurasilë të mölë .
Ipo ofurufu
Ni Ipo ofurufu, nëtiwöki ati redio transceivers wa ni paa lati
se aabo fun idamu si awön eroja. Nigbati flight mode ti wa ni mu
šišë, o beere löwö rë lati yan ipo nigbamii ti o ba tan foonu rë:
• Deede – išë ni kikun
• Ipo ofurufu – išë die to lopin
O lee lo onišë Orin ni Ipo ofurufu.
Lati mu akojö ašayan ipo ofurufu šišë
• Lati imurasilë yan Ašayan > Eto > ni Gbogbogbo taabu
> Ipo ofurufu > Fihan ni bërë.
PIN ati PUK rë (Kökörö Sisina fun Ara ëni) ti pese lati ödö onišë
nëtiwöki rë.
Bi ifiranšë naa PIN ti ko tö Iye igbiyanju ti o ku: ba han
nigbati o satunkö PIN rë, o të PIN tabi PIN2 ti ko baamu ni.
Lati šii kaadi SIM rë
1 Nigbati Ti dina mö PIN ti han, yan Šii silë.
2 Tun PUK rë të sii ko si yan O dara.
3 Të PIN titun sii ko si yan O dara.
4 Tun PIN titun të si ko si yan O dara.
Lati tan-an titiipa kaadi SIM
1 Lati imurasilë yan Ašayan > Eto > ni Gbogbogbo taabu
> Aabo > Awön titipa > Idaabobo SIM > Idaabobo.
2 Tun PIN rë të sii ko si yan O dara.
3 Yan Tan.
Lati šatunkö PIN rë
1 Lati imurasilë yan Ašayan > Eto > ni Gbogbogbo taabu
Dië ninu awön išoro yoo beere ki o pe onišë nëtiwöki rë. Fun
atilëyin dië ë sii lö si www.sonyericsson.com/support.
Titunto si ipilë
Ti o ba ni awön išoro pëlu foonu rë, gëgëbi baibai iboju tabi didi
iboju tabi awön išoro lilö kiri, o yë ki o tun foonu naa to. Ti o ba
yan Tun gbogbo rë to, gbogbo data olumulo gëgëbi awön
olubasörö, ifiranšë, aworan ati ohun ti paarë.
Lati tunto gbogbo eto
• Lati imurasilë yan Ašayan > Eto > ni Gbogbogbo taabu
> Tun gbogbo rë to > Tesi. > Tesi.
Awön ifiranšë ašiše
Ti dina mö PIN
O ti të koodu PIN rë sii löna ti ko tö nigbakanna. SIM rë ti wa ni
titi pa. Ti SIM rë pa pelu koodu PUK rë eyi ti a pese pëlu koodu
PIN nipasë onišë nëtiwöki rë.
Lati šii kaadi SIM silë
1 Të koodu PUK sii ko si yan O dara.
2 Të PIN titun sii ko si yan O dara.
3 Tun PIN titun të si ko si yan O dara.
Fi SIM sii
Ko si kaadi SIM ninu foonu rë tabi o ti fi sii löna ti ko tö. Gbiyanju
ökan tabi dië ë sii iwönyi:
• Yö kaadi SIM kuro ki o fi sii löna to tö.
• Wë asopö ori kaadi SIM ati foonu mö pëlu ohun gbigbönu
• Kan si onišë nëtiwöki rë lati gba kaadi SIM titun.
Awön ibere to wöpö
Foonu ko še tan-an
Gbiyanju lati gba agbara si foone titi yoo fi pari gbigba agbara.
So šaja pö mö (rii daju wipe aami agbara ori šaja köju si öna
oke) gba agbara si foonu naa fun wakati 3.5. Aami batiri loju
iboju ko le han titi foonu yoo fi gba agbara fun ögbön išëju 30.
Nko le lo Ayelujara tabi MMS
Ridaju pe alabapin foonu ti še awön atilëyin gbigbe data, ati eto
pipe ninu foonu rë.
Nko le ranšë awön iföröranšë (SMS)
Ridaju pe oni ipa išë nömba arin ninu foonu rë.
Foonu ko šee wa-ri fun awön ërö miiran nipa lilo išë-öna
ërö alailowaya Bluetooth
O ko i ti tan isë Bluetooth. Ri daju isöwö-riran ni o seto si
Fi foonu han. Wo Tan-an išë Bluetooth loju iwe 30.
Bawo ni mo še ma yi ede foonu pada bi?
1 Lati imurasilë yan Ašayan > Eto > ni Gbogbogbo taabu
We, Sony Ericsson Mobile Communications AB of
Nya Vattentornet
SE-221 88 Lund, Sweden
declare under our sole responsibility that our product
Sony Ericsson type AAB-1880013-BV
and in combination with our accessories, to which this declaration re lates is in
conformity with the appropriate standards EN 301 511:V9.0.2, EN 300 328:V1.7.1,
EN 301 489-7:V1.3.1, EN 301 489-17:V1.2.1 and EN 60 950-1:2006, following
the provisions of, Radio Equipment and Telecommunication Terminal Equipment
Directive 1999/5/EC.
A ti mu awön ibeere Ilana ti R&TTE šë (1999/5/EC).
GSM 900/1800
Itösona olumulo yi jë atëjade nipasë Sony Ericsson Mobile Communications AB
tabi ajö agbegbe to somö, laisi atilëyin öja eyikeyi. Awön didara si jë iyipada si
Itösona olumulo yi fi agbara muse pëlu ašiše, laisi fun alaye to wa, tabi awön didara
si awön eto ati/tabi ërö, le jë šiše nipasë Sony Ericsson Mobile Communications
AB ni igbakugba laisi akiyesi. Iru ayipada yoo, sibësibë, šee dapö si iwe titun Itösöna
olumulo yi.
Gbogbo ëtö ti wa ni ipamö.
Gbogbo awön aworan apejuwe wa fun aworan apejuwe nikan o le ma še dede foonu
gangan. Foonu alagbeka rë ni agbara lati gba lati ayelujara, töju kosi firanšë siwaju
akoonu, fun apeerë. awön ohun orin ipe. Lilo iru akoonu bë le ni ihamö tabi awön
ëtö ënikëta, pëlu šugbön ko ni opin si hihamö labë awön ofin didakö to wulo. Iwö,
ni kii še Sony Ericsson, ni o šee igbökanle lodidi fun akoonu afikun ti o gba wöle
lati ayelujara si tabi firanšë siwaju lati foonu alagbeka rë. Šaaju si lilo akoonu afikun
eyikeyi, jöwö mö daju wipe ipinnu lilo rë ni iwe-ašë daradara tabi bibëkö ti gba ašë.
Sony Ericsson ko še onigböwö išëdede, iyege tabi didara eyikeyi afikun akoonu
tabi akoonu eyikeyi miiran ti ënikëta. Laisi alaye-pipe një Sony Ericsson duro
ni önaköna fun aibojumu lilo akoonu afikun tabi akoonu ënikëta miiran.
Sony, M2 ati Memory Stick Micro jë aami-išowo tabi aami-išowo ti a forukösilë
ti Sony Corporation. Ericsson jë aami-išowo tabi aami-išowo ti a forukösilë ti
Telefonaktiebolaget LM Ericsson. Išë Predictive Text asötëlë jë lilo labë iwe-ašë
lati ajö-ëgbë Zi Corporation. Bluetooth ati ami Bluetooth jë ami išowo tabi ami
išowo ti a forukösilë ti Bluetooth SIG Inc. Ati ami bëë ti a lo fun ni Sony Ericsson
wa labë iwe- ašë. Aami Idanimö ötadidan, PlayNow ati TrackID jë awön aami-išowo
tabi aami-išowo ti a forukö silë fun ni Sony Ericsson Mobile Communications AB.
PlayNow ni ko si tabi ki a se atilëyin fun ni gbogbo öja tabi gbogbo agbegbe. Orin
TrackID™ ni agbara nipasë Gracenote Mobile.
Microsoft, Windows ati Vista jë awön aami-išowo tabi aami-išowo ti a forukösilë
ti Microsoft Corporation ni Orilë Amërika ati/tabi awön orilë-ede miiran. Öja miiran
ati awön orukö ile-išë ti a mënuba ninu rë le jë awön aami-išowo awön onihun wön.
Akiyesi: Sony Ericsson awön olumulo ni imöran lati še afëyinti fun alaye data ti ara
wön. Öja yi ni aabo nipasë awön ëtö ohun-ini imö ti Microsoft kan. Lilo tabi pinpin
kaakiri iru išë öna ti ita öja yi ti ni idinamö laisi iwe-a šë lati Microsoft. Awön onihun
akoonu lo Windows Media digital rights management technology (WMDRM) lati
daabobo ohun ini imö, pëlu awön ašë lori ara. Ërö yi nlo software WMDRM lati
wöle si akoonu idaabobo WMDRM. Ti software WMDRM ba kuna lati daabobo
akoonu, onihun akoonu le sö fun Microsoft lati fagilee agbara software’s lati lo
WMDRM lati mu šišë tabi daakö akoonu to ni idaabobo. Fifagilee ki yoo pa akoonu
ti ko ni idaabobo lara. Nigbati o ba gbaa awön iwe-ašë lati ayelujara fun akoonu
to ni idaabobo, o ti gba pe Microsoft le wa ninu akojö fifagilee pëlu awön iwe-ašë.
Awön onihun akoonu le beere pe ki o še igbesoke WMDRM lati wöle si akoonu
wön. Ti o ba kö igbesoke, iwö kii yoo ni anfani lati wöle si akoonu ti nbeere igbesoke.
Awön Ilana ifiranšë si ilë okeere: Öja yi, pëlu software tabi data išë öna eyikeyi ti
o wa ninu rë tabi ti o ba öja na de, le jë ohun ti a sörö le lori ni awön ofin išakoso
ifiranšë si ilë okeere ti orilë AMËRIKA, pëlu Ofin Abojuto Ifiranšë si ilë okeere ati
awön ilana ti o somö ati awön eto iyööda ti orilë AMËRIKA nipasë abojuto Išakoso
Ohun-ini Ajeji ti Apakan Yara-išë Išuna ti orilë AMËRIKA, o le jë afikun ohun ti
a sörö le lori si awön ilana ifi öja ranšë tabi gbe wöle lati ilu okeere ni awön orilëede miiran. Olumulo ati eyikeyi olohun-ini öja gba lati ni ibamu to le pëlu gbogbo
iru awön ilana ati gbigba wipe išeduro wön ni lati gba eyikeyi iwe-ašë ti a beere
lati fi öja ranšë si ilu okeere, tun-fi ranšë, tabi gbe öja yi wöle lati ilu okeere. Laisi
iwön öja yi, pëlu software eyikeyi ti o wa ninu rë, le ma še gbaa lati ayelujara, tabi
bibëkö ti firanšë si ilu okeere tabi tun firanšë (i) sinu, tabi si ti orilë-ede tabi olugbe
ti, tabi nkankan ni, orilë Kuba, Iraaki, Iraani, Ariwa Koria, Sudaanu, Siria (bi iru akojö
le šee tunwo lati igba de igba) tabi orilë-ede eyikeyi si eyiti orilë AMËRIKA ti ni
awön ëru ifi ofin de mölë; tabi (ii) si ënikëni tabi nkankan lori akojö Apakan Išura
orilë AMËRIKA fun Awön olugbe Pataki ti a Yan tabi (iii) ënikëni tabi nkankan lori
akojö idinamö ifiranšë si ilu okeere eyikeyi miiran ti o le muduro lati igba de igba
nipasë Ijöba orilë AMËRIKA, pëlu šugbön ko ni iwön si Apakan Išowo ti Akojö
Eniyan ti a Kö ti orilë AMËRIKA tabi Akojö Nkankan, tabi Apakan Ipinlë Akojö
Iyööda Ti ko ni idagbasoke kiakia.
Awön ëtö to ti ni ihamö: Lo, išëpo meji tabi ifihan nipasë ijöba Amërika si kok o-örö
awön ihamö bi a ti šeto siwaju ninu awön ëtö inu data imö-ërö ati awön gbolohun örö
Software Kömputa ninu DFARS 252.227-7013(c) (1) (ii) ati FAR 52.227-19(c) (2)
bi iwulo fun.